News

Ifoya ko si fawọn to wa ni Oke-Okun lakooko yii lati fi owo wọn gbe nnkan rere ṣe lori ile gbigbe - Oludasile Pelican Valley

Ifoya ko si fawọn to wa ni Oke-Okun lakooko yii lati fi owo wọn gbe nnkan rere ṣe lori ile gbigbe – Oludasile Pelican Valley

Dokita Babatunde Adeyẹmọ, gbajumọ ninu awọn to n ta ilẹ, to ṣee gbọkanle,laini idunkoko kankan, to nileeṣẹ Pelican Valley Nigeria Limited, Ọmọwe Babatunde Adeyẹmọ, ti rọ gbogbo awọn to wa ni Oke-okun lati fọkan wọn fun idokoowo lori ohun to jẹ mọ ilẹ ati dukia lakooko yii, nitori pe igba yii lo dara ju laini ifoya kankan.

Read more

Ifoya ko si fawọn to wa ni Oke-Okun lakooko yii lati fi owo wọn gbe nnkan rere ṣe lori ile gbigbe – Oludasile Pelican Valley Read More »

Asiko ree f'awọn ọmọ Naijiria ti wọn n gbe niluu Oyinbo lati fi owo dokoowo lori ile gbigbe - Alaṣẹ Pelican Valley

Asiko ree f’awọn ọmọ Naijiria ti wọn n gbe niluu Oyinbo lati fi owo dokoowo lori ile gbigbe – Alaṣẹ Pelican Valley

Alaṣẹ, apaṣẹ ati oludasilẹ ileeṣẹ Pelican Valley Nigeria Limited, Ọmọwe Babatunde Adeyẹmọ ti sọ pe ko si asiko to dara fun awọn ọmọ orileede Naijiria lati fi owo wọn dokoowo lori ọrọ ile ati dukia si Naijiria, to kọja asiko yii.

Read more

Asiko ree f’awọn ọmọ Naijiria ti wọn n gbe niluu Oyinbo lati fi owo dokoowo lori ile gbigbe – Alaṣẹ Pelican Valley Read More »

WeCreativez WhatsApp Support
We are here to answer your questions. Ask us anything!
Scroll to Top