Asiko ree f'awọn ọmọ Naijiria ti wọn n gbe niluu Oyinbo lati fi owo dokoowo lori ile gbigbe - Alaṣẹ Pelican Valley

Asiko ree f’awọn ọmọ Naijiria ti wọn n gbe niluu Oyinbo lati fi owo dokoowo lori ile gbigbe – Alaṣẹ Pelican Valley

Alaṣẹ, apaṣẹ ati oludasilẹ ileeṣẹ Pelican Valley Nigeria Limited, Ọmọwe Babatunde Adeyẹmọ ti sọ pe ko si asiko to dara fun awọn ọmọ orileede Naijiria lati fi owo wọn dokoowo lori ọrọ ile ati dukia si Naijiria, to kọja asiko yii.

Read more

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

WeCreativez WhatsApp Support
We are here to answer your questions. Ask us anything!
Scroll to Top